Lyrics

Gbogbo ero ti ngo ro l'oni, rere ni o (rere ni o, rere) Gbogbo ọrọ ti ngo fọ loni, ye, rere ni o (rere ni, rere ni) Rere loko, lodo, loke, nilẹ, lọjọ gbogbo Oun gbogbo ti nwo ṣe loni rere ni o (rere ni o, rere) Gbogbo irin ti ngo rin loni, ye, rere ni o (rere ni, rere ni) Rere ni'bere ni'dubulẹ, ni'dide ni'joko, lọjọ gbogbo Rere loko, lodo, loke nilẹ, lọjọ gbogbo Oun gbogbo ti mo wo loni rere ni o (rere ni o, rere) Ibi gbogbo ti mo tẹ loni, ye, rere ni o (rere ni, rere ni) Rere niyẹwu, nigbagede, l'òwúrọ, lalẹ, lọjọ gbogbo Oun gbogbo ti mo ba dimu rere ni o (rere ni o, rere) Gbogbo ibi ti mo gb'ẹsẹ le, ye, rere ni o (rere ni, rere ni) Rere lotun losi, loko, lodo, lọjọ gbogbo Rere ni'bere, ni'dubulẹ, ni'dide, ni'joko, lọjọ gbogbo A ṣẹṣẹ bere ayọ ni o (ṣẹṣẹnṣẹṣẹ) A ṣẹṣẹ bere adun ni o (ṣẹṣẹnṣẹṣẹ) Ire otun lo wọlé o (ṣẹṣẹnṣẹṣẹ) Alafia gbe pẹlu awa (ṣẹṣẹnṣẹṣẹ) Ibalẹọkàn l'ogun awa o (ṣẹṣẹnṣẹṣẹ) Aikubaalẹ ọrọ (ṣẹṣẹnṣẹṣẹ) A ṣẹṣẹ bere igbadun ni o
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out