Lyrics

L'ọjọ yẹn l'agbo o (l'agbo àjọdun) Wọn n tẹ'lẹ pẹlu igboya (bi onile) Wọn n fi t'ẹrìn t'ayọ ṣe pọ o (l'agbo idunnu) Wọn o ba'ra wọn ja rara (rara o, rara o, rara o) Wo wọn b'ọn ṣe n jo o e Wo wọn b'ọn ṣe n kọ'rin ayọ Wo wọn b'ọn ṣe n gb'ẹsẹ jẹjẹ Àwọn ọmọ amilẹgẹlẹgẹ (amilẹgẹ) Àwọn ọmọ alajọdun de o Àwọn ọmọ amilẹgẹlẹgẹ (amilẹgẹ) Àwọn ọmọ alajọdun de o Ẹni ba wọn pe jo o (l'agbo àjọdun) Ko le ṣá i jo'jo yẹn o (ijo aláyọ) Ọmọdé ma n bẹ níbẹ o (àwọn agba pẹlu) Gbogbo wọn n ṣe pele o (jẹjẹ, jẹjẹ, jẹjẹ) Wo wọn b'ọn ṣe n jo o e Wo wọn b'ọn ṣe n kọ'rin ayọ Wo wọn b'ọn ṣe n gb'ẹsẹ jẹjẹ Àwọn ọmọ amilẹgẹlẹgẹ (amilẹgẹ) Àwọn ọmọ alajọdun de o Àwọn ọmọ amilẹgẹlẹgẹ (amilẹgẹ) Àwọn ọmọ alajọdun de o Wo wọn b'ọn ṣe n jo o e Wo wọn b'ọn ṣe n kọ'rin ayọ Wo wọn b'ọn ṣe n gb'ẹsẹ jẹjẹ Àwọn ọmọ amilẹgẹlẹgẹ (amilẹgẹ) Àwọn ọmọ alajọdun de o Àwọn ọmọ amilẹgẹlẹgẹ (amilẹgẹ) Àwọn ọmọ alajọdun de o Amilẹgẹlẹgẹ (amilẹgẹ) Àwọn ọmọ alajọdun de o Amilẹgẹlẹgẹ (amilẹgẹ) Àwọn ọmọ alajọdun de o Àwọn ọmọ amilẹgẹlẹgẹ (amilẹgẹ) Àwọn ọmọ alajọdun de o
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out