Top Songs By Dreez MaliQ
Similar Songs
Credits
AUSFÜHRENDE KÜNSTLER:INNEN
Dreez MaliQ
Künstler:in
BhadBoi OML
Leadgesang
KOMPOSITION UND LIEDTEXT
Dreez MaliQ
Komponist:in
BhadBoi OML
Komponist:in
PRODUKTION UND TECHNIK
Dreez MaliQ
Produzent:in
Lyrics
Ire wọle o, Baba, mo wa f'ọpẹ fun ọ
Mo sun layọ, mo ji layọ, mo wa yin ọ logo
Dide mo de o, Baba Mimọ o, mo wa f'ọpẹ fun ọ
Mo sun layọ, mo ji layọ, mo wa yin ọ logo
Bi mo ṣe n jade lọ, Baba, ṣọ mi ninu aye
Bi mo ṣe n jade lọ, Baba, Baba, ma jẹ n tan 'nu aye
Protect all my friends, and my family, yeah
B'araiye gbogun wa, You go set me free
Ma ṣe mi l'oniṣẹ, ori jẹ ki n ye
'Cause You are Merciful, oh Lord
I am going up
Up is the only way (eh-eh-eh-eh)
Never going down
Down with my enemies
I am going up
Up is the only way (eh-eh-eh-eh)
Never going down, down, down, down with my enemies, oh-oh
If e no be God, I no fit stand tall
Aye fẹ de'kisa fun ọmọ alaṣọ ọ
So many battles' wey I fight o
But I'm still here, mo wa d'ọmọ t'ọn sọ
Dide mo de o, Baba, mo wa f'ọpẹ fun ẹ
Jiji mo ji o daadaa
Shine Your mercy, Lord, ayy
Ara ọmọ o ya o, Baba, oh
I'm sick of envy, Lord
Ayy, dide mo de o, Baba Mimọ, oh
Mo kọ lọ n daro lọ, oh yeah
Oh my brother, oh my brother
Tori kan ba san o aran gba
Aba l'ọn daa o, maa j'ọba
Oju ẹ mo n wo, jọọ, ma lọ ka, eh-eh-eh, ọmọ-ọla
Ire wọle o, Baba, mo wa f'ọpẹ fun ọ
Mo sun layọ, mo ji layọ, mo wa yin ọ logo
Dide mo de o, Baba Mimọ, maa f'ọpẹ fun ọ-ọ
Mo sun layọ, mo ji layọ, mo wa yin ọ logo
Ara ọmọ o ya o, Baba (alubarika loju)
I'm sick of envy, Lord (k'Oluwa fere si o)
Dide mo de si ẹ lọrùn (ọmọ-ọla)
Mo kọ lọ n daro lọ ọ-ọ
(Kaycekeys on the beats)
(MaliQ)
Writer(s): Bhadboi Oml, Dreez Maliq
Lyrics powered by www.musixmatch.com