Music Video

Dreez MaliQ & Bhadboi OML - Way Up (Session Video)
Watch Dreez MaliQ & Bhadboi OML - Way Up (Session Video) on YouTube

Featured In

Credits

AUSFÜHRENDE KÜNSTLER:INNEN
Dreez MaliQ
Dreez MaliQ
Künstler:in
BhadBoi OML
BhadBoi OML
Leadgesang
KOMPOSITION UND LIEDTEXT
Dreez MaliQ
Dreez MaliQ
Komponist:in
BhadBoi OML
BhadBoi OML
Komponist:in
PRODUKTION UND TECHNIK
Dreez MaliQ
Dreez MaliQ
Produzent:in

Lyrics

Ire wọle o, Baba, mo wa f'ọpẹ fun ọ Mo sun layọ, mo ji layọ, mo wa yin ọ logo Dide mo de o, Baba Mimọ o, mo wa f'ọpẹ fun ọ Mo sun layọ, mo ji layọ, mo wa yin ọ logo Bi mo ṣe n jade lọ, Baba, ṣọ mi ninu aye Bi mo ṣe n jade lọ, Baba, Baba, ma jẹ n tan 'nu aye Protect all my friends, and my family, yeah B'araiye gbogun wa, You go set me free Ma ṣe mi l'oniṣẹ, ori jẹ ki n ye 'Cause You are Merciful, oh Lord I am going up Up is the only way (eh-eh-eh-eh) Never going down Down with my enemies I am going up Up is the only way (eh-eh-eh-eh) Never going down, down, down, down with my enemies, oh-oh If e no be God, I no fit stand tall Aye fẹ de'kisa fun ọmọ alaṣọ ọ So many battles' wey I fight o But I'm still here, mo wa d'ọmọ t'ọn sọ Dide mo de o, Baba, mo wa f'ọpẹ fun ẹ Jiji mo ji o daadaa Shine Your mercy, Lord, ayy Ara ọmọ o ya o, Baba, oh I'm sick of envy, Lord Ayy, dide mo de o, Baba Mimọ, oh Mo kọ lọ n daro lọ, oh yeah Oh my brother, oh my brother Tori kan ba san o aran gba Aba l'ọn daa o, maa j'ọba Oju ẹ mo n wo, jọọ, ma lọ ka, eh-eh-eh, ọmọ-ọla Ire wọle o, Baba, mo wa f'ọpẹ fun ọ Mo sun layọ, mo ji layọ, mo wa yin ọ logo Dide mo de o, Baba Mimọ, maa f'ọpẹ fun ọ-ọ Mo sun layọ, mo ji layọ, mo wa yin ọ logo Ara ọmọ o ya o, Baba (alubarika loju) I'm sick of envy, Lord (k'Oluwa fere si o) Dide mo de si ẹ lọrùn (ọmọ-ọla) Mo kọ lọ n daro lọ ọ-ọ (Kaycekeys on the beats) (MaliQ)
Writer(s): Bhadboi Oml, Dreez Maliq Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out