Lyrics

Baba wa ti nbe l'orun
Owo ni f'ooko re
Ife tire ni k'o se
L'ori oro aye wa
Baba wa ti nbe l'orun
Owo ni f'ooko re
Ko s'ohun t'o le f'Olorun lati se
Ko s'ohun t'o le f'Olorun lati se
O la'na s'okun, Jabesi i d'oloriire
Igba l'o yato
Omo ogbon ma gbagbe oh, ko s'ohun t'o le
Ko s'ohun t'o le f'Olorun lati se
Ko si o
Ko s'ohun t'o le f'Olorun lati se
Omo ma gbagbe, ko s'ohun t'o le
Iri a d'ojo, ojo a ro, ile a gba imisi
Ibukun a wa, ma gbagbe oh
O la'na s'okun, Jabesi i d'oloriire
Okun d'iyangbe ile, ohun t'aa ro pe o le sele
Igba l'o yato
Ko s'ohun t'o le f'Olorun lati se
Igbagbo l'a nilo fun'se iyanu re
Baba nla
Ireti l'a nilo fun'se iyanu re
Ife l'a nilo fun'se iyanu re, k'o le se
Ko s'ohun t'o le omo, f'Olorun lati se
Igbagbo l'a nilo fun'se iyanu re, Baba nla
S'e iranti awon ise iyanu t'o ti sele
Ireti l'a nilo fun'se iyanu re, Baba iyanu
Koda iyanu n sele l'ojoojumo
Baba, agbara t'o gbe iseda ro, iyanu ni
Ife l'a nilo fun'se iyanu re, k'o le se
Ko s'ohun t'o le omo, f'Olorun lati se
Omo ma gbagbe o, omo ma gbagbe o
Igbagbo t'o duro giri
Igbagbo l'a nilo fun'se iyanu re, Baba nla
Bo ti wu k'o ri, ojumo a mo kii ye
Awon ise iyanu t'o n sele
Ireti l'a nilo fun'se iyanu re, Baba iyanu
Ojumo a mo ko ni ye
Oorun a wo, ile a su ko ni ye
Iyanu l'emi mo pe won je o nigbagbogbo
Ife l'a nilo fun'se iyanu re, k'o le se
Won po gan, won a de se, won a de se omo
Ko s'ohun t'o le f'Olorun lati se
Omo ma gbagbe o, omo ma gbagbe o
Ko si o
Ko s'ohun t'o le f'Olorun lati se
S'e o gbagbe sa, opo l'a ri ka, opo ni o tie l'akoole, opo l'a nri sugbon t'a o ko'bi ara si
Ko s'ohun t'o le f'Olorun lati se
Ko si, ko si oo, Ó là'nà
O la'na s'okun, Jabesi i d'oloriire
Ngba t'aye ro p'o tan, nigba t'aye ro p'o tan o
Emi naa mo ni ijerisi temi
Igba l'o yato
Ko si, ko si oo
Ko s'ohun t'o le f'Olorun lati se
Baba wa ti nbe l'orun, owo ni f'ooko re
Oniiyonu julo Baba, ife e tire ni k'o se
L'órí ọ̀rọ̀ ayé ẹ wa
Baba wa ti nbe l'orun, owo ni f'ooko re
Bi mo ba f'oju okan wo okun t'o pinya
Eru a ba mi o
Ara mi a se giri wipe Alagbara ni Baba a wa
Igba l'o yato omo eniyan o je lo gbeje
Tete ko se temi l'O n beere, A se'yanu
Bi mo ba f'oju okan wo okun t'o pinya
Eru a ba mi o
Ara mi a se giri wipe Alagbara ni Baba a wa
Igba l'o yato omo eniyan o je lo gbeje
Tete ko se temi l'O n beere, A se'yanu
A se'yanu
A se'yanu
A se'yanu, A se'yanu
A se'yanu
Nise l'okan dabi p'o le gan
O dabi p'o le
Oniyonu ni Baba wa
Aa mu aanu wa
A se'yanu omo ma gbagbe
A se'yanu
Tete ko se temi l'O n beere o
A se'yanu
Ko s'ohun tí O le se awa ni k'a t'ero ara wa pa k'a ye'ra wa wo k' a bo s'inu ife Oluwa gangan
A se'yanu
Eni ikosile wa nise l'o kan dabi i p'o le gan a se'yanu o
A se'yanu
Tete ko se temi l'O n beere o
A se'yanu
Written by: Sola Allyson, Wilson Joel
instagramSharePathic_arrow_out