Lyrics

Ijapa o nibi t'o nlo Kele, kele, o nrin, o nlo Araiye nyimu, o nlo Ero wa, ero lo, o nlo Ko gba agidi O ro bi A, B, D Ko ba koju mo tie Ti mo koju mo temi Bi a ba fi eyin si owo otun Ka feyin sowo osi K'awa f'eyin rin lati ahin titi de Iseyin Eni ma yini, a yini Eni o ni yini, ko ni yini Se bo'timo, ore Se bo'timo, ore mi Se bo'timo, mama Se bo'timo, baba mi Won ntan e Dakun ye ma tan'ra re Tire, ntire Ye ma ko'ra re Bo ba sare, bo subu Iwo lo lara re Bo'le, bo'ro Ore, ye ma paara 're Ko gba agidi O ro bi A, B, D Ko ba koju mo tie Ti mo koju mo temi Bi a ba fi eyin si owo otun Ka feyin sowo osi K'awa f'eyin rin lati ahin, titi de Iseyin Eni ma yini, a yini Eni o ni yini, ko ni yini Se bo'timo, ore Se bo'timo, ore mi Se bo'timo, mama Se bo'timo, baba mi
Writer(s): Ashimi Ibrahim Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out