Credits
AUSFÜHRENDE KÜNSTLER:INNEN
Brymo
Künstler:in
KOMPOSITION UND LIEDTEXT
Olawale Olofo'ro
Songwriter:in
PRODUKTION UND TECHNIK
Mikkyme Joses
Produzent:in
Lyrics
Èmi ni, èmi lẹni náà
Ọkùnrin mẹta àtààbọ t'ọn forin kọ
Èmi ni, èmi l'ọmọ náà
Ọkùnrin mẹrin àtààbọ, wọn ń tẹnu mọ
Mo lanu, mo sọrọ
Mo yọ àáké, mo fọ ọrọ
Ọmọ ọlọọfọọrọ
Mo j'àkàrà ọfọọrọ
Èmi ni áà, emi ni óò
Èmi mà l'ẹni t'ọn sọ nígboro
Èmi ni yáà, èmi ni yóò
Àwọn màmá gan ń sòró ní pópó
Wọn lémi l'àkọkọ
Wọn lémi l'àkọkọ, oh-oh
Wọn lémi l'àkọkọ, oh-oh
Wọn lémi l'àkọkọ, oh-oh
Èmi ni ọkùnrin náà
T'áwọn màjèsín ń sọ pé m'orin gan
Èmi ni, èmi l'ọmọ náà
Gbogbo ará àdúgbò ló ń tẹnu mọ
Èmi bàbá olówó
Mo ṣ'òwò, mo jèrè
Ìwà àti ọpọlọ ló ń lò
Àwọn ọtá ti ru póò
Èmi ni áà, emi ni óò
Èmi mà l'ẹni t'ọń sọ nígboro
Èmi ni yáà, èmi ni yóò
Àwọn ọmọge ń rèdí ní pópó
Ah, wọn lémi l'àkọkọ (iwọ l'àkọkọ)
Wọn lémi l'àkọkọ, oh-oh (iwọ l'àkọkọ oh)
Wọn lémi l'àkọkọ, oh-oh (iwọ l'àkọkọ)
Wọn lémi l'àkọkọ, oh-oh (iwo l'àkọkọ oh)
Wọn lémi l'àkọkọ (iwọ l'àkọkọ)
Wọn lémi l'àkọkọ, oh-oh (iwọ l'àkọkọ oh)
Wọn lémi l'àkọkọ, oh-oh (iwọ l'àkọkọ)
Wọn lémi l'àkọkọ, oh-oh (iwọ l'àkọkọ, oh)
Writer(s): Olawale Olofo'ro
Lyrics powered by www.musixmatch.com