Apparaît dans
Titres les plus populaires de BhadBoi OML
Titres similaires
Crédits
AUSFÜHRENDE KÜNSTLER:INNEN
BhadBoi OML
Künstler:in
KOMPOSITION UND LIEDTEXT
BhadBoi OML
Songwriter:in
Paroles
Ọrọ ngbè 'nu mi s'ọrọ
Oosha ngbè 'nu mi fọhun
Sango ngbè 'nu mi sh'ọrò
Ẹluku ngbè 'nu mi fọhun
And, I no too like to dey vex
Ẹyin ẹlẹnu mẹta, logo Benz
Pikin wey say papa no go sleep, hin mama no go vex
Many pepper no go rest, ẹgbá bẹh (ẹgbá bẹh)
Chocolate and Caramel (ooh-wee)
Obi ati orogbo (ooh-wee)
Ẹyin l'ẹma sin iya yin (ooh-wee)
Oku oun sàn'wò posi, sh'òmọ? (Ooh-wee)
Chocolate and Caramel (ooh-wee)
Ebu ati ogogoro (ooh-wee)
Ọla nbi wọn ninu (ooh-wee)
Onkawọn l'árá (ooh-wee)
Let's take it back to bad-good days, old days, those days t'ẹn f'oribẹ
I told dem, I told dem, ounjámi l'árá jẹ, but na tip of the iceberg
Apọnle diẹ-diẹ-diẹ l'árá nfẹ oh
Afọshẹ nbẹ t'oba fẹ oh, ma l'álá ri wèrèy
Ṣọpọna nimi, moni k'ẹma rimi fin
It-It is what it is, me I kuku come in pеace
Kilimanjaro lẹ sọh fun pe "ráráo gá"
Ẹlọ sọh fun oga yin pe "Ọmọ Ọla sọh pe, ori wọn o da"
Wọnle-wọnle, wọnle, wọn o ba
Wa wo Ronaldinho, o ma mọ pe Messi gan o da
And, I no too like to dey vex
Ẹyin ẹlẹnu mẹta, logo Benz
Pikin wey say papa no go sleep, hin mama no go vex
Many pepper no go rest, ẹgbá bẹh (ẹgbá bẹh)
Chocolate and Caramel (ooh-wee)
Obi ati orogbo (ooh-wee)
Ẹyin l'ẹma sin iya yin (ooh-wee)
Oku oun sàn'wò posi, sh'òmọ? (Ooh-wee)
Chocolate and Caramel (ooh-wee)
Ebu ati ogogoro (ooh-wee)
Ọla nbi wọn ninu (ooh-wee)
Onkawọn l'árá (ooh-wee)
Chocolate and Caramel (ooh-wee)
Ebu ati ogogoro (ooh-wee)
Ọla nbi wọn ninu (ooh-wee)
Onkawọn l'árá (ooh-wee)
Á wè Coco mọ'wè oh, á wè Coco mọ'wè oh
Á wè koriko, á wè koriko-oh
Lááji na, fááji na
Koleyara l'ofi man', koleyara l'ofi mayan
Lááji na
Writer(s): Vid Vucenovic, Akinyinka Kuham, Etus Favour Chukwuemeka
Lyrics powered by www.musixmatch.com