Paroles

(M-M-Muderer) Them cover thier head, carry AK twen I don't know the thing you una dey call am AK25, (AK47) yes Them say make we no talk I say na lie my daddy G.O say I will talk Correct, I will talk, I am a chosen I am a chosen (I am a chosen) I am a chosen you wicked man who are you? (I am a cho-cho) Ayy, ẹni tọ'lọrun pé, ohun lọ'lọrun yàn Ko to di wo-wo-wo (kò to di wo-wo-wo) Ọmọ Ọlọhun ń gbọ' Ọlọhun ń gbọ' ó (Ọlọhun ń gbọ' ó) Ọmọ Ọlọhun ń gbọ' (ọmọ Ọlọhun ń gbọ') I wan give testimo-o, I get one testimony I wan give testimo-o, I get one testimony Mo wá dupẹ to ko mi yọ Otún jẹ k'okó mi yọ, hmm-hmm osé Yee, Bilikisu má do mí lọ, pa-pa-pa, supe daada Èlò ni mo gbà ti má gbé raga I wan give testimo-o, I get one testimony (Èlò ni mo gbà ti má gbé raga) I wan give testimo-o, I get one testimony (Èlò ni mo gbà ti má gbé raga) Ehh, èmi ó sakọ mọ ohh (uh fafa lé wọn) Emi ó sakọ mọ ohh (uh fafa lé wọn) Normally na wake an bake up Call my dealer, e never wake up Mo si crusher mo ri gbẹ ẹsin Miracle working Jesus Genesis touch my heart Exoduxe burst my brain ohh After this one (after this one) E mi o mu igbó mọ ó (e mi o mu igbó mọ ó) I wan give testimo-o, I get one testimony Mo wá dupẹ to ko mi yọ Otún jẹ k'okó mi yọ, hmm-hmm osé Yea, Bilikisu má do mí lọ, pa-pa-pa, supe daada Èlò ni mo gbà ti má gbé raga I wan give testimo-o, I get one testimony (Èlò ni mo gbà ti má gbé raga) I wan give testimo-o, I get one testimony (Èlò ni mo gbà ti má gbé raga) Ehh, emi ó sakọ mọ ohh (uh fafa lé wọn) Emi ó sakọ mọ ohh (uh fafa lé wọn) Ehh, emi ó sakọ mọ ohh (uh fafa lé wọn) Emi ó sakọ mọ ohh (uh fafa lé wọn) Ehh, emi ó sakọ mọ ohh (uh fafa lé wọn) Emi ó sakọ mọ ohh (uh fafa lé wọn) (I am a chosen) Who mix this (Murderer)
Writer(s): Elijah Olanite, Akinyinka Oladimeji Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out