Paroles

Ìyàwó kàn mí npa mi lo, gere Wọn l'olufoya ni mí oh oh Ọkùnrin tó lè fẹ mẹta, merin ah ah Pe mo sà, mo sà, ẹrú dé mí mọlẹ Ọkàn mi ti fọ' wẹwẹ Ọkàn mi ti pin yẹ'lẹ'yẹ'lẹ' Nígbà míràn n'ifẹ fẹ ma wù Láti ibì ẹwà kóró ẹ'mi mi Kò tún ní wú Mo mọ bò ṣe burúkú O fi lè lẹ tìpẹ'tipẹ' Má yọ apá mí fún ọ Òun ló n'ba ẹ' nnú jẹ Tí 'nu mi ndún Kò dára Ọkàn mi ti fò wẹwẹ Ọkàn mi ti pin yẹ'lẹ'yẹ' Nígbà míràn, n'ifẹ fẹ má wù Láti ibì ẹwà kọ'rọ' èmi mi Kò tún ní wú
Writer(s): Olawale Ibrahim Ashimi Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out