Letras

[Verse 1]
Iṣe mi ni
Ka ma feedu fọnna
Eruku o wọnu ọbẹ mi
Bi ẹni n logi iṣana
Ọmọ Iya Agba
Awọn Aaba n mẹni mo jẹ
Ọmọde to mọwọ wẹ
Mo n bagba jẹun
[Chorus]
Bẹ ba ri mi nigboro
Bẹ ba mọ ki mi
Bẹ naka si mi
Ẹ pe mi l'afeedufọnna
Afeedufọnna
Feedu fọnna o
Bẹ ba ri mi nigboro
Bẹ ba ma ki mi
Bẹ naka si mi
Ẹ pe mi l'afeedufọnna
[Verse 2]
Ọrọ to wa nilẹ
Ọrọ gbogbo wa ni
Alawọ ara a mọra wa
Igbakugba awa ti kọja aala
Ibi o bara rẹ, ah
Jọ ṣe daadaa nibẹ
Ọmọde to mọwọ wẹ
O ma bagba jẹun, ah
[Chorus]
Bẹ ba ri mi nigboro
Bẹ ba mọ ki mi
Bẹ naka si mi
Ẹ pe mi l'afeedufọnna
Afeedufọnna
Feedu fọnna o
Bẹ ba ri mi nigboro
Bẹ ba ma ki mi
Bẹ naka si mi
Ẹ pe mi l'afeedufọnna
[Outro]
Afeedufọnna
Feedu fọnna o
Bẹ ba ri mi nigboro
Bẹ ba mọ ki mi
Bẹ naka si mi
Ẹ pe mi l'afeedufọnna
Written by: Olawale Olofo'ro
instagramSharePathic_arrow_out