Canciones similares
Créditos
AUSFÜHRENDE KÜNSTLER:INNEN
Brymo
Künstler:in
KOMPOSITION UND LIEDTEXT
Olawale Olofo'ro
Songwriter:in
Letras
[Verse 1]
Igba o lọ bi orere
Bo ba koro o ṣi maa dun, ah
Ẹni to ni suuru ki i ṣeeyan kekere
Bo ba kanlẹ, o ṣi maa goke, ah
Bo o ba ṣehun t'ọn fe, wọn maa kẹyin si ẹ, ẹh a ẹh
Bo ba ṣe tirẹ o, o ma jẹ ire fun ẹ, ẹh a ẹh
[Chorus]
Ọlanrewaju ọmọ ọba
E ma suure dagba o
Wọn ni ko o ṣe were, rọra ṣe
E ma suure dagba o
Olootọ ko ni ku si bi ọtẹ o
Olanrewaju ọmọ mi
E ma suure dagba o
[Verse 2]
Igba o lọ bi orere
Bọmọde o ku o, o ṣi maa dagba
Ṣọra fun ija, ṣọra fẹgbẹkẹgbẹ
Ohun ti o to o, o ṣi maa pọ danu, ah
Gbogbo ẹni a bi lo ma ku, eh, ẹh a ẹh
Iwa taa wu lo ma ku, ah, eh, ẹh a ẹh
[Chorus]
Ọlanrewaju ọmọ ọba
E ma sure dagba o
Wọn ni ko ṣe were, rọra ṣe
E ma suure dagba o
Olootọ ko ni ku sibi ọtẹ o
Ọlanrewaju ọmọ mi
E ma suure dagba o
[Outro]
Olootọ ko ni ku sipo ika o
Olootọ ko ni ku sibi ọtẹ o
Ọlanrewaju ọmọ ọba
E ma sure dagba o
Ọlanrewaju ọmọ mi
E ma sure dagba o
Written by: Olawale Olofo'ro