Music Video

Featured In

Credits

AUSFÜHRENDE KÜNSTLER:INNEN
Rybeena
Rybeena
Stimme und Gesang
KOMPOSITION UND LIEDTEXT
Adewale Atanda
Adewale Atanda
Songwriter:in
PRODUKTION UND TECHNIK
TBM
TBM
Produzent:in

Lyrics

(M-M-Murderer) (Rybeena dè, Rybeena dè) (Agba Singing ti dè, ojurá wọn lọ, t'ijakádi kọ) Mo gbè ekelebe wọ club, o mu Bellaire (oh) L'ábá dè'lè tàn, l'obá lọn ṣhèèpo (what?) T'oba jẹrèkere, stop, mio bá ẹ fẹyin Sáárè funmi l'ori, ọmọ, time dey go Don't please my heart, please my body Ṣh'omọ pè ọlọmọge yápá nigboro I no fit lose my feelings for the Benjamin You no fit enter me, ayy-ahh Ṣho mọn ro, nigga mi? (Oh-ohh) Ọmọ, ko sijá ni church, ṣ'ádurá, kin ṣ'ámin (oh-ohh) Ọmọ ọpẹ no fit give up, ko ṣhati ri lapii (oh-ohh) Ṣhèbi ọrẹ nigga mi kàn l'ofi colo yi Backii L'obá tun kigbè "gbámi gbámi" oh Ẹ wá wo olè, ájibolè O ni, ko kin ṣh'olè, ori, l'ogbè Ẹ wá wo olè, ájibolè O ni, ko kin ṣh'olè, ori, l'ogbè Iṣho Baba Ruka, èyin lo yọ, ẹmi o bọ Iṣho Baba Ruka, èyin lo yọ, ẹmi o bọ Ayy-ah, ṣho mọn ro, nigga mi? (Oh-ohh) Ọmọ, ko sijá ni church, ṣ'ádurá, kin ṣ'ámin (oh-ohh) Ọmọ ọpẹ no fit give up, ko ṣhati ri lapii (oh-ohh) Ṣhèbi ọrẹ nigga mi kàn l'ofi colo yi Backii L'obá tun kigbè "gbámi gbámi" oh Ẹ wá wo olè, ájibolè O ni, ko kin ṣh'olè, ori, l'ogbè Ẹ wá wo olè, ájibolè O ni, ko kin ṣh'olè, ori, l'ogbè Iṣho Baba Ruka, èyin lo yọ, ẹmi o bọ Iṣho Baba Ruka, èyin lo yọ, ẹmi o bọ
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out