Lyrics

Iyin ati ope loye fun baba Iyin ati ope fun messiah Oba ti o pa wa mo ninu ewu Iyin ati ope fun Jehovah Bi mo ba lawo ti o po to one thousand Ko ti e le to lati yin oooo Agaba igbega ti mo wa yii ni next level Iyin ati ope fun Jah Jehovah Iyin, ogo ye oo Modupe o baba mi ogo ye o Emi ti won ko bata fi ra atupa lo jo si Mo wa di eni ajitona fun araye o wa So mi di ayan mo wa di ayan oloyimomo Oro mi di ijo Oro mi dijo e wa bamiyo eba mi dupe Ewabamiyo loni aye ye mi Moroju rere olorun ogo ye o ose olorun ti o so mi di ayan oloyinmomo Bi edumare ba le se se ti mo dide ri n gbogbo aye yin yio bami fi Iyin fi ijo yin baba jake jado agbaye okiki a kan je ko sese daabobo Mi o awon toku to n ba binu je ki inu won ro Je ki inu won ro ki a le fi idunnu jaye pe bi won ba wa ko wipe awon O gba wa se won mose fi won se sample iya ki won le mo pe iwo lo Oba Bi mo ba se re lowo Ayefele bi mo ba gbo ilu bi mo ba ri ilu inu mi a dun Ara mi a ya gaga ose olorun ti o so mi di ayan oloyinmomo Ba se lu lu yi bi e se n jo iku o ni Pawa o aarun o ni se yin o ka jo ma se pepepe Ayefele tunti de alujo tun ti de o ya wa ka jojo ilu oloyinmomo Hypertension o le raye bi ilu ba n dun alujo po ninu ilu yii e mo na Pa ronu ti ore beere wa ka jo jo ironu pupo Hypertension ma lo n fa wa beere oya beere oya beere wa ka jo jo 2ce Ojo ti o ro ti o kun ikoko ni agbala ojo oun lo ro sinu apere ti ko De kun so ikoko wa yo wipe apere o le mu ojo dani e bami so fun ikoko Ki ikoko mama yo mo asiko n bo wa fun apere bi ojo ba da tan apere n Bo wa ko ore oko bi ojo ba ti da igba eda asiko eda wa lowo baba Oke pa ironu ti ore asiko re bo wa De pa ironu ti o ya bere mo le si jo Ayefele tunti de alujo tun ti de o ya wa ka jojo ilu oloyinmomo Hypertension o le raye bi ilu ba n dun alujo po ninu ilu yii e mo na Pa ronu ti ore beere wa ka jo jo ironu pupo Hypertension ma lo n fa wa beere oya beere oya beere wa ka jo jo Ti o ba rii se ma se pe padii e lo le because onitiri ola tun le Saalaye be e mo ko si owo loni owo n bo bi o dola ko si ola loni ola N bo bo dola agan mama beru mo omo n bo wa asiko eda igba eda wa lowo Baba oke then ironu pupo hypertension ma de Lo tun fa wa pa ironu oya bere mo le si ijo Ayefele tunti de alujo tun ti de o ya wa ka jojo ilu oloyinmomo Hypertension o le raye bi ilu ba n dun alujo po ninu ilu yii e mo na Pa ronu ti ore beere wa ka jo jo ironu pupo Hypertension ma lo n fa wa beere oya beere oya beere wa ka jo jo Be emi ko olorun mi o ori mo mu waye ori owo ni ori mo Mu wa ye oriola ni agbon ti o ni omi ninu ko si eni ti o mo idi re
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out