Featured In

Credits

AUSFÜHRENDE KÜNSTLER:INNEN
Prophet Hoteyin John
Prophet Hoteyin John
Künstler:in
KOMPOSITION UND LIEDTEXT
Prophet Hoteyin John
Prophet Hoteyin John
Komponist:in

Lyrics

Prelude Ha Ha, Ha ha, ha ha Mi emi iye Re s'arin wa ha ha Ha ha Emi imu Re, Seb'owun lo bori ha ha Ha ha Seb'owun lo l'ana s'arin okun ha ha O t'akoko ka wa p'atewo Tongues Wa o wa Wa o wa o wa oo Wa o wa, wa o wa Olorun Mose o, wa, Orimolade o Wa o wa, gbe'ra n'ile ko ma bo l'odo mi Wa o wa, tongues Wa o wa Olorun Mose o, wa Kare omo Ahola Oke osebu mo fe ri O l'aarin wa Tongues Wa o wa, won de t'iye t'iye l'owo o Wa o wa, won de ti'ja ti'ja wa Wa o wa, Olorun Mose o, wa mi'ra l'ori ite mi'raaa Wa o wa, wa o wa Baba mi o Wa o wa, o d'ade od'Oba Wa o wa, Olorun Mose o, wa, ninu emi o d'Oba 2 Cor10:4 – For the weapons of our warfare are not carnal But mighty through God To the pulling down of strong holds Serafu nko E k'orin JAH, e k'orin ogun E k'orin JAH JAH, e k'orin ogun Awon Kerubu naa nk'orin E k'orin JAH, e k'orin ogun, Tongues E k'orin JAH JAH, e k'orin ogun Serafu nko, e k'orin JAH, e k'orin ogun Awon Kerubu t'won nk'orin E k'orin JAH JAH, e k'orin ogun Tongues, e k'orin JAH, e k'orin ogun Tongues, e k'orin JAH JAH, e k'orin ogun Kerubu nko E k'orin JAH, e k'orin ogun Serafu nkorin E k'orin JAH JAH, e k'orin ogun E ma bo l'odo mi. Tongues E k'orin JAH, e k'orin ogun Korin s'oke e E k'orin JAH JAH, e k'orin ogun Kerubu nko E k'orin JAH, e k'orin ogun Serafu nkorin E k'orin JAH JAH, e k'orin ogun Move, Holy Ghost Move, Akoko to o, Holy Ghost Wa s'ise agbara, Show your power Tongues Move, Tongues Holy Ghost Move, Holy Ghost Heh, Baba Mimo o Show your power Rin, Emi Mimo Rin Rin Rin Rin Rin, Emi Mimo Rin de'le Baba mi o F'agbara Re han Rin de'le Iya mi ja fun mi Rin, Emi Mimo Mu ki egun idile o tan Rin, Emi Mimo Ba'n fo pepe won tutu F'agbara Re han Tongues F'agbara Re han Tongues F'agbara Re han Tongues F'agbara Re han Ma w'oju eyan F'agbara Re han Tongues F'agbara Re han Ran mi l'owo o, Tongues Egbe Aladura mura Ki yoo si nkan Jesu y'o di yin l'amure Ki yoo si nkan Ẹ gbe ida 'sẹgun soke Kil' ohun ti mba yin l'ẹru? Esu ko le ri wa gbe se Ko le si nkan B' IKU ba n gbogun, s'ọmọ Ajasẹgun Ẹ ma foya Ẹ ja bi ọmọ igbala Ẹ t'esu pa B'ayé ba n gbogun s'ọmọ Ajasẹgun Ẹ ma foya Ẹ ja bi ọmọ igbala Ẹ t'esu pa B'esu ba n gbogun s'ọmọ Ajasẹgun Ẹ ma foya Ẹ ja bi ọmọ igbala Ẹ t'esu pa B'ajẹ ba n gbogun s'ọmọ Ajasẹgun Ẹ ma foya Tongues Ẹ ja bi ọmọ igbala Ẹ t'esu pa B'oso ba n gbogun s'ọmọ Ajasẹgun Ẹ ma foya, Heh Ẹ ja bi ọmọ igbala Ẹ t'esu pa B'ọta n gbogun s'ọmọ Ajasẹgun Ẹ ma foya Ẹ ja bi ọmọ igbala Ẹ t'esu pa Oya f'owo agbara Re kan mi Na'wo agbara Re Na'wo agbara Re F'owo agbara Re kan mi Na'wo agbara Re Na'wo agbara Re Yah! F'owo agbara Re kan mi o Na'wo agbara Re Na'wo agbara Re Oba to l'agbara to po Na'wo agbara Re Mo n duro de O Na'wo agbara Re Olugbeja k'eru o b'on'ija, Tongues Na'wo agbara Re Na'wo agbara Re Ba n ja, Ba n ja Na'wo agbara Re Ole ni mi, mi ole ja Na'wo agbara Re Won duro de Baba mi o Won ni ta lo de? Na'wo agbara Re Wa na'wo agbara re o Na'wo agbara Re Tongues Jah Micheal sokale Lati gbeja'wa eyan re Tongues Tan pe o ni'gba gbogbo Lati le bori esu Jah Micheal sokale Jah-Micheal-sokale-e Lati gbeja'awa eyan re Tongues Tan pe o ni'gba gbogbo Lati le bori esu Jah Micheal sokale On'ida ina o, ma fi wa sile bai Lati gbeja'awa eyan re Tan pe o ni'gba gbogbo Ma je, ma je, b'a ba n pe o Lati le bori esu Revelations 5: 5b,12b "weep not: behold Of David hath prevailed,to open the book And to loose the seven seals thereof Worthy is the Lamb that was slain, to receive power And riches, and wisdom And strength, and honor, and glory, and blessings." Oya Power be Power Be, Power Be, Power Be Riches Be, Riches Be Wisdom Be, Wisdom Be Strength Be, Strength Be Honor Be, Honor Be Glory Be o, Glory Be Blessing Be Blessing Be, Blessing Be, Blessing Be Wa fun wa n'ibukun ka le ma r'ona lo l'odo Re Blessing Be, Blessing Be, Blessing Be Oya Power be Power Be, Power Be, Power Be Riches Be, Riches Be Wisdom Be, Wisdom Be Strength Be, Strength Be Honor Be, Honor Be Glory Be o, Glory Be Blessing Be o, Blessing Be Blessing Be oo, Blessing Be Ma bo l'odo mi Blessing Be Je'o de'le mi Blessing Be Power Be, Power Be Riches Be, Riches Be Wisdom Be o, Wisdom Be Strength Be, Strength Be Honor Be, Honor Be Glory Be, Glory Be Blessing Be o, Blessing Be Ma bo l'odo wa Blessing Be Tongues Blessing Be Blessing Be Emi ni El El-Sahula Ọba Ajasẹgun ni mi Emi ni Jehofa Hullam Ọba Awimayẹhun Ẹ ma yọ ninu ore mi K'ẹ si ma dupẹ pẹlu Emi ni Asaholah Ọba a-fi-di-p'ọ-tẹ-mọlẹ Oba o, Oba Oba o, Oba Oba Ajijasegun, Oba Oba Afidip'otemole Oba Oba ooo Oba o, Oba Oba o, Oba Oba Ajijasegun, Oba Oba Afidip'otemole Oba Oya Oba Afidip'otemole Oba o Oba Afidip'otemole Oba Duro n'ibi ti won tin s'oro mi l'eyin l'ati s'emi n'ibi Oluwa Oba Afidip'otemole Oba Won ko'ra won jo, a o tun won ka, kaakiri Oba Afidip'otemole Oba N'ibi ti Ba'a mi ti duro imo ota o le se, Tongues Oba Afidip'otemole Oba Heh! Holy Jah, Holy Jah Holy Ja fun wa, Holy Jah, eo Holy Jah Oba to f'iwa mimo b'ori Holy Jah Holy Ja fun wa Wa ja fun wa oo Holy Jah Holy Jah, Holy Jah Holy Ja fun wa, Holy Jah o e Holy Jah, Holy.Jah Holy Jah Holy Ja fun wa, Holy Jah Mimo Jah, Mimo Jah Mimo ja fun wa, Mimo Jah eeee Mimo, Jah oo Mimo Jah, Mimo Jah Mimo ja fun wa, Mimo ja fun wa o Mimo Jah Mimo ja fun wa, Mimo Jah eeee Mimo ja fun wa, Mimo Jah Ina jo jo jo o, ina jo Ina jo, ina ina jo Ina Jo, Ina jo HA! jo jo o, ina jo Ina jo, ipa ese wa jo Ina jo, emi agbere oo Ina jo jo jo o, ina jo Emi iro, emi ija, emi ibinu Ina jo, ibinu odi, emi eke sise Ina jo jo jo o, ina jo Ina jo, ina ina jo Ina jo, ina jo jo jo o, ina jo Tongues Ina jo, Ma w'oju e Ina jo jo jo o, ina jo Ina jo, ina jo jo jo o, ina jo Fire burn, fire fire, burn Fire burn, eeee Fire burn burn burn, fire burn Oh, Fire burn all my infirmity Fire burn, fire burn burn burn, fire burn The spirit of anger, strife, lust Fire burn, robbery and lies Fire burn burn burn, fire burn The spirit of sodomy, sorcery and death Fire burn, fire burn burn burn, fire burn Oh Fire burn, fire fire, burn eeee Fire burn, fire burn burn burn, fire burn Awọn igbi omi wọnyi Ti f'agbara wọn lu mi ri Wọn ko le se ọ n'ibi mọ Emi ni; mase bẹru Oya Eli-Jah Eli-Jah ja ja o Eli-Jah ja ja, Tongues Eli-Jah ja Eli Ja fun wa Eli-Jah ja ja o Eli-Jah ja ja Eli-Jah ja Eli Ja fun wa Oya Eli-Jah Eli-Jah ja ja o Eli-Jah ja ja Awon aja aye yi po, won k'oju ija si wa Eli-Jah ja Eli Ja fun wa Baba mimo o Eli-Jah ja ja o Eli-Jah ja ja Gba wa l'owo awon akeke Eli-Jah ja Awon akeke Eli Ja fun wa Tongues Eli-Jah ja ja o, Tongues Eli-Jah ja ja Eli-Jah ja Eli Ja fun wa, oju re la n wo o Baba mimo Eli-Jah ja ja o Eli-Jah ja ja Eli-Jah ja Eli Ja fun wa 1 Kings 19: 11 – O si wipe, Jade lo Ki o si duro lori oke niwaju Oluwa. Si kiyesi i Oluwa koja, Iji nla ati lile si fa awon oke nla ya O si fo awon apata tutu niwaju Oluwa San bi ara o, Ja bi iji San bi ara o, Ja bi iji Lati' yara oke, sise Re San bi ara o, Ja bi iji, Ma ja fun mi San bi ara o, Ja bi iji, Ja fun gbogbo wa. Heh! Lati' yara oke, sise Re San bi ara o, Ja bi iji Oba mi a d'agba ma te'pa ma paro oye, Ja bi iji Ogbe inu wundia s'ola, ogbe inu adelebo s'ogo, Ja bi iji Ja bi iji, Heh! Lati' yara oke, sise Re Baba o San bi ara o Ja bi iji, Tongues San bi ara o, Ja bi iji Lati' yara oke, HEH! sise Re Oya, Lati' yara oke, sise Re e-e-e Lati' yara oke, sise Re Lati yara oke Baba sise agbara ti o po Lati' yara oke, sise Re Je ki ahon ina Re ba le wa, ran wa l'owo k'ale bori Baba Lati' yara oke, sise Re Ipa re t'on be l'oke-e bori fun gbogbo wa se Lati' yara oke, sise Re Iji, Iji, rin l'arin wa Tongues Iji, Iji, rin l'arin wa Ma w'oju eyan Iji, Iji, rin l'arin wa Eyi t'oku ninu panti ogun Iji, Iji, rin l'arin wa Gba won danu s'inu ibu Iji, Iji, rin l'arin wa Ma je a ri won mo Ogun t'o ti se ogbodo tun gbe'ri mo Iji, Iji, rin l'arin wa Ba ngba panti kuro Iji, Iji, rin l'arin wa Ajagomom Busawuu Ajagomom Butari Ọmọ Mimọ ti sẹgun A dupẹ lọwọ Baba Opo kan Maleka kan Opo kan Maleka kan E wa w'awon to sokale Baba oo Opo kan Maleka kan Ina kan Maleka kan Ina kan Maleka kan E wa w'awon to tan'mole Jesu oo Ina kan Maleka kan Oro kan Maleka kan Oro kan Maleka kan E wa w'awon to so'ro Re Emi mimo Oro kan Maleka kan Isaiah 21:9 - And, behold, here cometh a chariot of men With a couple of Horsemen. And he answered and said Babylon is fallen, is fallen; and all the Graven images of her gods he hath broken, unto the ground Fallen Babylon, fallen, fallen, fallen Fallen Babylon, fallen Fallen Babylon, fallen Fallen Babylon, fallen Fallen Babylon, fallen Fallen Babylon, fallen Fallen Babylon, fallen Fallen Babylon, fallen Wo, Babyloni, Wo, Tongues Wo, wo, wo Wo, Babyloni, Wo Wo, Babyloni, Wo Wo, Babyloni, Wo Wo, Babyloni, Wo Ma wo, ma wo Wo Ma wo lu'le Wo Ma dide mo Rara Wo A bori re l'ojo toni o Wo Ipa Olorun bori ipa t'esu Wo Wo Esu subu l'atori oke bi ara Wo Wo Tongues Wo Tongues Wo Ma subu, ma subu Wo Iwo ati awon oluranlowo re gbogbo o Wo Wo Tongues Wo Wo Wo Esu, mobolowo Re Esu, mobolowo Re Esu, mobolowo Re Esu, mobolowo Re Olugbala fimi j'oye Esu, mobolowo Re Olugbala fiwa j'oye Esu, mobolowo Re Ade Mose, l'ori awon omo Mose Esu, mobolowo Re Esu, mobolowo Re o Esu, mobolowo Re Esu, mobolowo Re Esu, mobolowo Re Olugbala fimi j'oye Esu, mobolowo Re Olugbala fimi j'oye se Esu, mobolowo Re E w'ade Mose, l'ori awon omo Mose Esu, mobolowo Re Ayọ ni fun wa loni Laholah, ẹ bu s'ayọ Jesu Balogun nla wa Ti sẹgun iku fun wa Laholah! Laholah! Laholah! Laholah! Laholah! Laholah! E ke Halleluyah! Halleluyah!
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out