Lyrics
Mo ni ife re nitooto
N 'o puro
N'o puro oo
Mo mo ogbe Okan re nitooto
Amo emi yato oo
N 'o puro
N o gbe o rin do
Ese re oni kan 'mi
N o ba o roke
Ese re oni kan le
Mo shey ogbingbin
Je n ba o lo
Ibi o ba nnlo
N 'o ba o re
N 'o ba o re
Ayanfe, je n ba o rele oo
Ibi o ba nlo
N o ba o lo
N o ba o lo
Won ni ki layanmo mi
Mo ni Iwo ni
Won ni ki layanmo mi
Ife re ni
Irin wa ti di ajorin
Ebo wa ti di ajogbe
N o puro oooo
N o puro ooo
N o gbe o rin do
Ese re oni kan mi
N o ba o ro ke
Ese re oni kan le
Ayanfe Jen ba o dele
Ibi o ba nnlo
Ibi o ba nnlo
Ayanfe Jen ba o dele
Ibi o ba nlo oo
N o ba o lo ooo
Ila lomo oriki ila oooo
Ogiri lomo oriki ooobe ooo
Ayanfe dakun dabo shey temi
Ibi o ba nnnlooo ooo
Ayanfe, Ayanfe ee mi
Ayanfe je n ba o dele oo
Ibi o ba nnlooo
Ibi o ba nnlo oo
Ayanfe dakun shey temi
Irin wa ajorin
Ebo wa ajogbe
Iku wa ajoku
(Keyboard sounds)
Lyrics powered by www.musixmatch.com