Featured In

Credits

AUSFÜHRENDE KÜNSTLER:INNEN
JayMikee
JayMikee
Künstler:in
Joshua Mike-Bamiloye
Joshua Mike-Bamiloye
Künstler:in
Bunmi Akinleye
Bunmi Akinleye
Künstler:in
KOMPOSITION UND LIEDTEXT
Joshua Isreal
Joshua Isreal
Songwriter:in
Joshua Mike-Bamiloye
Joshua Mike-Bamiloye
Songwriter:in
Bunmi Akinleye
Bunmi Akinleye
Songwriter:in

Lyrics

E ba mi ki Olurapada E ba mi ki Olurapada Nitori to shey oun pupo fun Omo araye Nitori anu re duro Lai Lai E bami ki Olurapada E bami ki Olurapada Apata aye raye mo ki o o baba mi Alagbara giga giga giga Alagbara to n gba mi lowo ajunilo Kii ba ti la gbara re Ko se un ti la gbara re Olugbala Oludande Olurapada Olugbeja Oluranlowo Ata aiye se e e Ato rise Mo ti Fi Jeus shey abo Oun ni ibi isadi mi Lowo lowo iranlowo baba ti dide iranlowo fun mi A ti gbemiga Ori Apata aye raye a ko ni shi mi ni po rara A ti ramipada A ti so mi do omo Mo jade ninu Idalebi Ah ah ah ah Mo gba idalare Ninu Jesu Oluwa E ba mi ki Olurapada E ba mi ki Olurapada Nitori to shey oun pupo fun Omo araye Nitori anu re duro Lai Lai E bami ki Olurapada E bami ki Olurapada Ara ba ri biti Ari bi rabata Gba ni gba ni ti aye n saya Gba ni gba ni ti Orun n bo Olori Ogun Asaju Ogun Akeyin Ogun Akikanju loju Ogun Iwo la gba ni lowo ija Baba mi arogun da ade Arogun ma ti di Olugbeja Mi oh oh oh Gba ni gba ni Mu ni mu ni Yo ni yo ni La ni la ni Olusegun Aja segun O gbe ni ni ija ke ru o bonija lojo ija Baba mi onikan gbe rare nija Ta ni Iwo oke ni waju Zerubabeli Lojiji odi dan dan ki e di ite mole Mo gboju mi soke ni bi iranlowo mi yio a ti wa Iranlowo mi n be ninu oruko oluwa ah ah ah ah A ti gbe mi nijaaa Mo ti ju asegun lo E ba mi ki Olurapada E ba mi ki Olurapada Nitori to shey oun pupo fun Omo araye Nitori anu re duro Lai Lai (Chants) E ba mi ki Olurapada E ba mi ki Olurapada Nitori to shey oun pupo fun Omo araye Nitori anu re duro Lai Lai E ba mi ki Olurapada E ba mi ki Olurapada
Writer(s): Bunmi Akinleye, Joshua Isreal, Joshua Mike-bamiloye Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out