Similar Songs
Lyrics
Sebi nitori ogo ni
Nitori ogo ni
Ohun ti oju ologo bari ooo
Nitori ogo ni
Sebi nitori ogo ni ke
Nitori ogo ni
Ohun ti oju ologo ba ri ooo
Notori ogo ni ooo
Aimoye ogun ti o ma bori
Ki a to fi oruko Olorun pon e le
Aimoye iji ti o ma ja
Ki a to pe o lalagbara
Aimoye ina ti a ma la koja
Ki Wura aye eni le tan yinriyinrin
Aimoye abunkun ta ma kan
Ki aponle to de ba omo ologo
A dabi pe Olorun o si lori ite mo
A wa jobi pe majemu o si fun onigbagbo mo
Igba to ba le, to dabi wipe ko si ireti mo
Ogo lo fe de yen
Iranlowo n bo wa
Iyanu ti fe sele
Orun ire ti fe si
Omije o ni je o ri
Sebi ni tori ogo ni oooo
Ni tori ogo ni
Ohun ti o mu olododo bu si gbe ooo
Ni to ri ogo ni
Sebi ni tori ogo ni oooo
Ni tori ogo ni
Ohun ti oju ologo bari laye ooo
Ni to ri ogo ni
A se Olorun mo si
A se Olorun dami mo
Gbogbo ohun ti mo la koja laye
Fun ogo oluwa ni
A se Olorun mo si
A se Olorun dami mo
Gbogbo ohun ti mo la koja laye
Fun ogo oluwa ni
Olorun ri e oooo
Olorun ri e oo
Bi o se n jade lowuro to n wole la le
Olorun ri e oooo
Olorun ri e oooo
Olorun ri e oo
Awon ti won ro e pin
Ti won ni o lo se rere laye
Olorun ri uh uh uh eh ooooo
A dabi Olorun o si lori ite ooo
A dabi pe Olorun o si lori ite mo
A wa jobi pe majemu o si fun onigbagbo mo
Igba to ba le, to dabi wipe ko si ireti mo
Ogo lo fe de yen
Iranlowo n bo wa
Iyanu ti fe sele
Orun ire ti fe si
Omije o ni je o ri
Sebi nitori ogo ni
Nitori ogo ni
Ohun ti oju ologo bari ooo
Nitori ogo ni
Lyrics powered by www.musixmatch.com