Lyrics

Ijoba Re de, ase Re bere Agbara wa, o ba sori mi Ijoba Re de, ase Re bere Agbara wa, o ba sori mi Ijoba Re de, ase Re bere Agbara wa, o ba sori mi Ijoba Re de, ase Re bere Agbara wa, o ba sori mi Ijoba Re de, ase Re bere Agbara wa, o ba sori mi Ijoba Re de, ase Re bere Agbara wa, o ba sori mi Ijoba Re de, ase Re bere Agbara wa, o ba sori mi Okunkun ka, Imole de Iranwo de, gbogbo ise n kun mi lowo Ise mo wa se, ise Imole, ma a s' aseye Ma a rin arinto, ma a rin arinye Agbara wa, o ba sori mi Okunkun ka, Imole de Iranwo de, gbogbo ise n kun mi lowo Okunkun ka, Imole de Iranwo de, gbogbo ise n kun mi lowo Ise mo wa se, ise Imole, ma a s' aseye Ma a rin arinto, ma a rin arinye Agbara wa, o ba sori mi Mo f'ebun sola o Bee naa lo ri Mo f'ebun mi fogo fun Oluwa t'O l'ebun mi Bee naa lo ri Ijoba Re de o Owo yida lori iseda mi Ase Re lat' orun bere, bee naa lo ri Owo yida lori iseda mi Isodotun de ba mi ni 'rin ajo mi Bee naa lo ri My men shall not be few, iranwo lat' origun mereerin agbaye temi ni Bee naa lo ri Awon t'o ma gbe mi, t' 'on ma sugba ohun mo gbe ka 'ri, won wa s'ona mi Bee naa lo ri Ijoba Re de o Owo yida lori iseda mi Si ti aanu, si ti iranwo, si ti iserere, bee naa ni Owo yida lori iseda mi Iranwo ti mi o ri ri, ma a ri lona gbogbo, bee naa ni Bee naa lo ri Aye mi a bu ola fun O, Eni ti O ni ebun mi, bee naa ni Bee naa lo ri Bee naa lo ri o, pelu ase Baba mi Owo yida lori iseda mi Mo ti di omo Apeere omo wa lara mi Owo yida lori iseda mi Agbara wa, O ba s'ori mi
Writer(s): Sola Allyson, Wole Adesanya Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out