Top Songs By King Sunny Ade
Credits
AUSFÜHRENDE KÜNSTLER:INNEN
King Sunny Ade
Künstler:in
KOMPOSITION UND LIEDTEXT
King Sunny Ade
Songwriter:in
Lyrics
Awo re gungun lobirin le ṣe
Awo gẹlẹdẹ lobirin le mọ
Bi obinrin fi oju doro, oro a gbe
Ékilo f'ọmọ odẹ, koma rìnrìn pado
Ékilo f'ọmọ odẹ, koma rìnrìn pado
Koma sesi fara ko odidan lojiji
Ìgbọràn sàn ju ẹbọ riru
Konko jabẹlẹ
Kaluku l'omi se ti é
Konko jabẹlẹ
Kaluku l'omi se ti e
Konko jabẹlẹ
Kaluku l'omi se ti e
Konko jabẹlẹ
Kaluku l'omi se ti e
Ki àwon ṣe tiwọn
Ki ẹyin ṣe t'ẹyin
Ki àwa ṣe t'awa
Konko jabẹlẹ
Kaluku l'omi se ti e
Amò ṣá
Ékilo f'ọmọ odẹ, koma rìnrìn pado
Ékilo f'ọmọ odẹ, koma rìnrìn pado
Koma sesi fara ko odidan lojiji
Ìgbọràn sàn ju ẹbọ riru
Writer(s): Sunny Ade
Lyrics powered by www.musixmatch.com