Lyrics

Adeniyi lo nki yin o A gbe t'ano danu, a gbe tuntun de Eyi ga (ah), oga lagaju, eyi ga A gbe t'ano danu, a gbe tuntun le Eyi ga, oga lagaju, eyi ga E ma gbo Iye ni ye eyele, iye ni ye eyele o Irubo ni raga ba l'orun Ayo mi k'ale o jare ni'le aye A ye mi l'oke okun A ye mi n'ile Naija A ye mi l'ode agbaye Ati ile ti mo n gbe A ye mi l'oke okun A ye mi n'ile Naija A ye mi l'ode agbaye Ati ile ti mo n gbe Ati inu ile ti mo n gbe (Ati inu ile ti mo n gbe) Ati inu ebi ti mo ni (aje) A ye mi l'oke okun A ye mi n'ile Naija A ye mi l'ode agbaye Ati inu ile ti mo n gbe A gbe t'ano danu, a gbe tuntun le Eyi ga, oga lagaju, eyi ga African beat, tutntun la gbe de Eyi ga, oga lagaju, eyi ga Iye ni ye eyele ni raga ba l'orun Eyi ga
Writer(s): Sunny Ade Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out