Lyrics

Igbeyin lo ju o, k'o mo Sebi 'bere, iyen ki s'onise Ka f'ara s'ise o to jare Ka f'ogbon si o, pelu suru A ti ru'bo oju, a s'oro didun, f'eni t'o nworan o Ka ma ma ko'se Awa ti d'omi siwaju, ka le te'le tutu Ka ma se r'oun ti o koja emi wa Sa ma gb'ese lokankan olufe Ojo ti da wayi, ko s'abata l'ona Fu'rugbin s'apa otun ati s'owo osi Oni ojo ibukun, ero ni gbeyin iji Ya mu'ra ode, olufe Ko s'oun t'o nbo wa to le si o ni'po Jijo re s'egbe otun ati s'apa osi Oni ojo idunnu, ojo ni gbeyin erun Igboya ni o gbe wa, k'o mo Oniberu, awon yen o ni le duro Ka be Olu-Aje o to jare Ka s'ise lo ju, lai s'awawi A ti ru'bo oju, a s'oro didun, f'eni t'o nworan o Ka ma ma ko'se Awa ti d'omi siwaju, ka le te'le tutu Ka ma se r'oun ti o koja emi wa Sa ma gb'ese lokankan olufe Ojo ti da wayi, ko s'abata l'ona Fu'rugbin s'apa otun ati s'owo osi Oni ojo ibukun, ero ni gbeyin iji Ya mu'ra ode, olufe Ko s'oun t'o nbo wa to le si o ni'po Jijo re s'egbe otun ati s'apa osi Oni ojo idunnu, ojo ni gbeyin erun Ah aaaaah Ah aaaaah A ti ru'bo oju, a s'oro didun, f'eni t'o nworan o Ka ma ma ko'se Awa ti d'omi siwaju, ka le te'le tutu Ka ma se r'oun ti o koja emi wa Sa ma gb'ese lokankan olufe Ojo ti da wayi, ko s'abata l'ona Fu'rugbin s'apa otun ati s'owo osi Oni ojo ibukun, ero ni gbeyin iji Ya mu'ra ode, olufe Ko s'oun t'o nbo wa to le si o ni'po Jijo re s'egbe otun ati s'apa osi Oni ojo idunnu, ojo ni gbeyin erun Ya mu'ra ode, ode Mu'ra ode, ode Mu'ra ode, ode
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out