Lyrics

Instrumental... Ẹ bá mí kí wọ́n ó Ẹ bá mí kí wọ́n ó Instrumental... Ilé owó ni ó wọ ó Ilé ọlá ni ó wọ Instrumental... Ṣe bí adé orí ọkọ ni wọn Obìnrin tó ni 'wà tó lẹwà Ìwúrí òbí ni wọn ò ma jẹ ó Obìnrin tó gbà ẹ'kọ' tó mu ló òòò Orí rẹ dára, orí rẹ sún wọn Ò dì adufẹ' olórí ọkọ Orí rẹ dára orí rẹ sun wọn O di abẹfẹ' ooo Instrumental... Ibadi aràn di ẹni amu ṣe yẹ yẹ o Bi ẹyẹ tí ó lápá Ibadi aràn di ẹni amu ṣe yẹ yẹ ooo Instrumental... Dúró ṣé òun obìnrin se o Gba'ye ṣe òun obìnrin se o Instrumental... Ẹ bá mí ki wọn o Ẹ bá mí ki wọn o Instrumental... Ilé owó ni ó wọ Ilé ọlá ni ó wọ Ilé owó ni ó wọ Instrumental... Ilé ọlá ni ó wọ Ilé owó ni ó wọ Ilé ọlá ni ó wọ
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out