Top Songs By Esther Igbekele JP
Credits
AUSFÜHRENDE KÜNSTLER:INNEN
Esther Igbekele JP
Künstler:in
KOMPOSITION UND LIEDTEXT
Esther Igbekele JP
Songwriter:in
Lyrics
Kini má fi dúpẹ, ọrẹ bàbá mi loke?
Kini má fi dúpẹ, ọrẹ bàbá mi loke?
Miraculously bàbá, you show your mercy o
Intentionally bàbá, you bless my life o
Kini má fi dúpẹ, ọrẹ bàbá mi loke?
Kini má fi dúpẹ, ọrẹ bàbá mi loke?
Gbọgbọ ète t'ọtá n lò, asán lásán bansa
Gbọgbọ ọna tí wón gbá, o dàrú mọ wọn lójú
Ẹni ba fẹ d'Ọlọrun wò, ofó lọ má ri mú
Ẹni ba fẹ d'Ọlọrun wò, ofó lọ má ri mú
Ọlọrun ló wà lẹyìn mi, ṣ'erò p'ojú lásán ni?
Ẹ má f'ojo b'ojo mi, bàbá n be lẹyìn mi
Lòwúrò tí mo ba ti ji, ojúmọ irẹ lo mo mi
Bàbá to n gbó àdúrà je kin ba're pàdé o
Bàbá to n gbó àdúrà, akorede ti dé ó
Kini má fi dúpẹ, ọrẹ bàbá mi loke?
Kini má fi dúpẹ, ọrẹ bàbá mi loke?
Miraculously bàbá, you show your mercy o
Intentionally bàbá, you bless my life o
Kini má fi dúpẹ, ọrẹ bàbá mi loke?
Kini má fi dúpẹ, ọrẹ bàbá mi loke?
Bi ba l'ẹgbẹrún ahan kò tó láti yín ọ, o
Òun to se l'ayé mi, loje kin ma yin ọ, o
Mio tètè mó pé bayi Ọlọrun ni eṣe dùn tó o
Ife to ni sí mi lọ je kí emi ma buga o
Ọlọrun ló wà lẹyìn mi, ṣ'erò p'ojú lásán ni?
Ẹ má f'ojo b'ojo mi, bàbá n be lẹyìn mi
Lòwúrò tí mo ba ti ji, ojúmọ irẹ lo mo mi
Bàbá to n gbó àdúrà, je kin ba're pàdé o
Bàbá to n gbó àdúrà, akorede ti dé ó
Kini má fi dúpẹ, ọrẹ bàbá mi loke?
Kini má fi dúpẹ, ọrẹ bàbá mi loke?
Miraculously bàbá, you show your mercy o
Intentionally bàbá, you bless my life o
Kini má fi dúpẹ, ọrẹ bàbá mi loke?
Kini má fi dúpẹ, ọrẹ bàbá mi loke?
Kini má fi dúpẹ?
Kini má fi dúpẹ?
Miraculously bàbá
Intentionally bàbá
Written by: Esther Igbekele