Apparaît dans
Titres similaires
Crédits
AUSFÜHRENDE KÜNSTLER:INNEN
Rybeena
Stimme und Gesang
KOMPOSITION UND LIEDTEXT
Adewale Atanda
Songwriter:in
PRODUKTION UND TECHNIK
Deobeatsmusic
Produzent:in
enobeatzz
Produzent:in
Spromson
Produzent:in
Haystixx
Produzent:in
Paroles
Gangster nimo ṣhán ṣhèè, timo pádè Mufu
I'm rolling with some rich thugs, èyàn Ikechukwu
Ṣh'omọ nkàn t'oju ri, kin to gbá Muzzle ni?
Ori gbona ninu dreadlock, mio lè sun mọju
Mum' mi o ṣhá mọ pè ọmọ yi ti kòbò
Ngbọ, won ni "mo l'ẹbu pẹlu ogogoro"?
Ẹshá má tẹlè mi, ẹyin jọnmọ mi
'Dewale Anobi l'oun gbọ, yeah
Igba lò yi, àwọn kàn ti hot nigbá kan-uh
Sọfun new taker yẹn, ko ṣhọrá gidigàn
'Cause the road to success, e dey hard gidigàn
I dey reason to dey four, yeah
T'oba dẹti l'owo, rá'ṣhọ gidigàn
K'owọ Off-Thug abi Zanku To The World
If you kpai yourself, ọmọ, life no go stop
Jẹun s'árá gidigàn
Èni tèrè oh (ohh)
Èji tèrè, moni ibèrè oh (ohh)
Ṣh'oyẹ k'ájẹpáko má wá sun lè oh? (Ohh)
O lon f'ọwọ osi lọ juwè ilè oh
Tinbá s'ọrọ, wọn á ni "mo tun ti dè oh" (ohh)
Oloba Ice áti Kurube oh (ohh)
Yankee tiji tipẹ, o tin run'lè oh
Show working, má pemi pè kin wá ja, owo ni ko pè mi fun
No dey whine yourself, nigga
The game is so bigger
Focused on my grind 'cause I no like fipá
You suppose get sense if you no get helper
Wọn fẹ mọ'ku tóh pá iyá teacher, ẹ lè bi Ifa
Igba lò yi, àwọn kàn ti hot nigbá kan-uh
Sọfun new taker yẹn, ko ṣhọrá gidigàn
'Cause the road to success, e dey hard gidigàn
I dey reason to dey four, yeah
T'oba dẹti l'owo, rá'ṣhọ gidigàn
K'owọ Off-Thug abi Zanku To The World
If you kpai yourself, ọmọ, life no go stop
Jẹun s'árá gidigàn
Èni tèrè oh (ohh)
Èji tèrè, moni ibèrè oh (ohh)
Ṣh'oyẹ k'ájẹpáko má wá sun lè oh? (Ohh)
O lon f'ọwọ osi lọ juwè ilè oh
Tinbá s'ọrọ, wọn á ni "mo tun ti dè oh" (ohh)
Oloba Ice áti Kurube oh (ohh)
Yankee tiji tipẹ, o tin run'lè oh
Show working, má pemi pè kin wá ja, owo ni ko pè mi fun (ahh)
Writer(s): Atanda Adewale
Lyrics powered by www.musixmatch.com