Letras
[Intro]
DJ Spinall
Davido
Wande Coal
Baddest (Iskaba eh)
[Verse 1]
Dey wanna know
Bi mo ṣe lọ'la bi mo ṣe n lowo
Dey wanna know eh
Bi mo ṣe'n kọle bi mo ṣe n fresh
Ọmọ dey wan know
Ọmọ dey wan know eh
[Chorus]
Kekere mo ti n gbowo (Gbowo)
Aboki wa n sare (Gbowo)
Mo dagba mo n tun ṣawo (Shawo)
Owo ti de e na wo ẹ sẹsẹ
Majesin olowo de (Owo de)
Ọmọde owo de
Odọmọde olowo olowo
Olowo ẹsẹsẹ
O ya shake your casanova o
(Ta lo wa o)
To ba ri mi ko bow down o (To ba ri mi ko bow down o)
Ka'jọ lọ'le ka stroll down (Ka'jọ lọ'le ki get down)
Ibilẹ lo'ma runtown o
To ba ri mi ko bow down
[Verse 2]
Tẹ'ba ti ṣe tan kẹ ya
Awọn ọmọ aye binu wọn fẹ gboriwọle
Ẹ ti ṣe tan ẹ yago lọna o
Ẹ yago
Tẹ'ba ti ṣe tan kẹ ya
Awọn ọmọ aye binu wọn fẹ gboriwọle
Ẹ ti ṣe tan ẹ yago lọna o, ẹ yago
[Verse 3]
Ever since I was seventeen, yeah
I've been getting it majorly
Diamonds all over me, yeah
Plenty blessings dey follow me, yeah
[Verse 4]
Everyday we high high high
Everyday we party go
The jobber dey fly fly fly
This girls makes me happy, girl
[Chorus]
Kekere mo ti n gbowo
Aboki wa n sare
Mo dagba mo n tun ṣawo
Owo ti de ẹ nawo ẹ sẹsẹ
Majesin olowo de
Ọmọde owo de
Ọdọmọde olowo olowo
Olowo ẹsẹsẹ
O ya shake your casanova o
To ba ri mi ko bow down
Ka'jọ lọ'le ka stroll down
Eh, ibilẹ lo ma runtown
To ba ri mi ko bow down
[Verse 5]
Ẹ ma lọ gboriwa kẹ yago
Ka wọn to lowo lọ'wọ k'ọn gboriwọle
Ma lọ gboriwa kẹ yago lọ'na mi o
[Verse 6]
I remember when I was sixteen
That time when I enter street
I've been chasing this money
Fire burn my enemies
[Verse 7]
Ebelebe ko sọmọ naa
Ebelebe ko sọmọ naa
Wande Coal David l'ọmọ naa
Ebelebe ko sọmọ naa
[Verse 8]
Wọn ni pe ko sowo
Ọmọ j'a wọle ka nawo
Talo ni ko sowo?
Ati kekere mo n ti pawo
[Chorus]
Kekere mo ti n gbowo
Aboki wa n sare
Mo dagba mo n tun ṣawo
Owo ti de ẹ nawo ẹ sẹsẹ
Majesin olowo de
Ọmọde owo de
Odọmọde olowo olowo
Olowo ẹ sẹsẹ
O ya shake your casanova o
To ba ri mi ko bow down o
Ka'jọ lọ'le ka stroll down
Eh, ibilẹ lo'ma runtown
To ba ri mi ko bow down
Olowo olowo
[Outro]
(Da'beats on the beats)
Olowo olowo
Olowo olowo
Written by: David Adeleke, Oluseye Sodamola, Oluwatobi Wande Ojosipe