Presentada en

Créditos

AUSFÜHRENDE KÜNSTLER:INNEN
Reminisce
Reminisce
Künstler:in
KOMPOSITION UND LIEDTEXT
Remilekun Khalid Safaru
Remilekun Khalid Safaru
Songwriter:in
PRODUKTION UND TECHNIK
Legendury Beatz
Legendury Beatz
Produzent:in

Letras

[Intro]
Ye be
Reminisce
Legendury Beatz
O ta lẹnu, leggo
Lọbalọba
Lọbalọba
Jọbajọba
Lọbalọba
Fakafaka
Leggo
Indomix
[Chorus]
I don go many places
I don see many faces
I don see many girls
Oyinbo ọmọ dudu ohun tẹ fi ṣaya yẹn it's too much
Ọmọ it's too much
Nnkan to pọn sẹyin yẹn, it's too much
Ohun tẹ fi ṣaya yẹn, it's too much
Hey eh eh!
[Verse 1]
Hey baby, njẹ irẹ mọ pe o ta ta?
N ba jẹ mo ṣori ni n ba la la
Nnkan to pọn sẹyin yẹn mo fẹ ba ba
Mo fẹ sundry ẹ, jẹ ki n sa sa
[Verse 2]
Wa n'bi baby, ki lo de to n ti'bẹ ti'bẹ?
Bi mo ṣe n wo ẹ yii, o ya ko ma ṣi'bẹ ṣi'bẹ
Ma lọ form bi ẹni pe o mọ pe mo ni'bẹ ni'bẹ
Ọrẹ mi l'Adigun, shii, mo milẹ milẹ
[Verse 3]
Check the profile mo n kọrin pẹlu lọbalọba
Awọn ọmọ ni London wọn n pe mi ni Mr lover lover
Shout out si awọn ọmọ ni Malay wire wire
Ọpa 6, padi Osha ijaya jaya
[Verse 4]
Belit idi mi yii ọmọ na Gucci Gucci
Wo bi wọn 'e ko mi jẹ ẹja tutu Sushi Sushi
Bata ti mo wọ Alexander McQueen ni
Ma tẹle wọn wa, o mọ pe swagger mi Supreme ni
[Chorus]
Shii, I don go many places
I don see many faces
I don see many girls
Oyinbo ọmọ dudu ohun tẹ fi ṣaya yẹn it's too much
Ọmọ it's too much
Nnkan to pọn sẹyin yẹn, it's too much
Ohun tẹ fi ṣaya yẹn, it's too much
Hey eh eh!
[Verse 5]
Okay, to ba de'le bo 'e yii o ma bimọ bimọ
O mọ bo ṣe tobi to ni ti n ba ti I bọ ti I bọ?
Wa pariwo "Ahh ahh" ti n ma kanlẹ kanlẹ
Emi janitor, shii, mo fọ'bẹ fọ'bẹ
[Verse 6]
Wọn n'ọ sọ fun ẹ tẹlẹ o ni k'ọn filẹ filẹ
Now you confirmed it, mo milẹ milẹ
Now you screaming, "Awww, it's touching my womb"
Wo bo ṣe n da everything ru ninu room room
[Verse 7]
Check profile wo awọn ti mo jẹ sẹyin sẹyin
B'ọn ṣe wa yẹn gbogbo wọn ni mo kan lẹyin lẹyin
Shoutout s'awọn ni Malay wire wire
Wa ni golf, Phillips Sodiq, wire wire
[Verse 8]
H-Money, oracle to n pe'ṣẹ wọle
Iwọ naa wo awọn ti mo ba to ko to wọle
Mana ti mo sa yii, shii, Nike
Ohun l'awọn Hausa n ki yaya aiki
[Chorus]
Shii, I don go many places
I don see many faces
I don see many girls
Oyinbo ọmọ dudu ohun tẹ fi ṣaya yẹn it's too much
Ọmọ it's too much
Nnkan to pọn sẹyin yẹn, it's too much
Ohun tẹ fi ṣaya yẹn, it's too much
Hey eh eh!
[Verse 9]
Owww, okay
Reminisce lo n bọ lọwọ kẹ filẹ filẹ
Abi ẹyin o da'yan mọ ni? Shi, Ibilẹ Ibilẹ
Emi nikan ma ni mo jẹ k'ọn ma kako kako
Wo b'ọn ṣe n jẹ awọn rappers, pako pako
[Verse 10]
Shoutout awọn ọmọ ni Gidi, wiki wiki
DJ music bring it back fiki fiki
Taken by surprise, ẹ labọ
Emi ni mo ni game yii, shi ,ẹ jabọ
[Chorus]
I don go many places
I don see many faces
I don see many girls
Oyinbo ọmọ dudu ohun tẹ fi ṣaya yẹn it's too much
Ọmọ it's too much
Nnkan to pọn sẹyin yẹn, it's too much
Ohun tẹ fi ṣaya yẹn, it's too much
Hey eh eh!
[Outro]
Afrobeat, eeeh
Legendury Beatz
Ẹ sare
I look like I send you?
Leggo
Hey!
Written by: Remilekun Khalid Safaru
instagramSharePathic_arrow_out