Vídeo musical

Zlatan - Super Power (Audio) ft. Davido, Yonda
Ver Zlatan - Super Power (Audio) ft. Davido, Yonda en YouTube

Presentada en

Créditos

AUSFÜHRENDE KÜNSTLER:INNEN
Zlatan
Zlatan
Künstler:in
PRODUKTION UND TECHNIK
Rexxie
Rexxie
Produzent:in

Letras

[Intro]
Wa, wọn a wa, wọn a wa niwa iyawo
Oloṣo ni wọn, wọn fẹ ka sọ wọn diyawo
Wa, wọn a wa, wọn a wa niwa iyawo
Aṣọmu ni wọn, wọn fẹ ka sọ wọn diyawo
[PreChorus]
I get power to do one hour
Your baby mama give you left over
She come my palace, she wan sleepover
This kind power na super power
[Chorus]
Wọn a wa, wọn a wa niwa iyawo
Oloṣo ni wọn, wọn fẹ ka sọ wọn diyawo
Wa, wọn a wa, wọn a wa niwa iyawo
Aṣọmu ni wọn, wọn fẹ ka sọ wọn diyawo
Kuro n'bẹ, this kind power na super
Nawọ si nnkan, to ba fẹ gbogbo ẹ la ma ra, wo
This kind na super power
Niṣo ninu yara ka lọ dara
[Verse 1]
Ori owo o dori ọmọ
A ti ri kini ka ṣe dori ọkọ
Orin dowo o, orin dọla
Orin di pound sterling, euro ati dollar
Nawonawo like a circle, irun were na my pillow
I know see Uche face as long as Uche know him place
Nawonawo like a circle, omi gutter na my Milo
I know send Uche face as long as Uche know him place
[PreChorus]
I get power to do one hour
Your baby mama give you left over
She come my palace, she wan sleepover
This kind power na super power
[Chorus]
Wọn a wa, wọn a wa niwa iyawo
Oloṣo ni wọn, wọn fẹ ka sọ wọn diyawo
Wa, wọn a wa, wọn a wa niwa iyawo
Aṣọmu ni wọn, wọn fẹ ka sọ wọn diyawo
Kuro n'bẹ, this kind power na super
Nawọ si nnkan, to ba fẹ gbogbo ẹ la ma ra, wo
This kind na super power
Niṣo ninu yara ka lọ dara
[Verse 2]
O ya who is in the garden? Jade si mi gba'bi
Owo wa n'lẹ jaburata o kun inu bag yii
O lọ n pe mi ni zaddy, baller bi ti Inzaghi
O loun fẹ owo, mo ni ko hit me bi ti Shaggi
[Verse 3]
Hello, baby how are you?
Ṣe daadaa, ko ṣe normal, ko ma lọ ṣiwa wu, wo
Hello, baby how are you?
Toke Makinwa tori yẹn na your sawawu
[PreChorus]
I get power to do one hour
Your baby mama give you left over
She come my palace, she wan sleepover
This kind power na super power
[Chorus]
Wọn a wa, wọn a wa niwa iyawo
Oloṣo ni wọn, wọn fẹ ka sọ wọn diyawo
Wa, wọn a wa, wọn a wa niwa iyawo
Aṣọmu ni wọn, wọn fẹ ka sọ wọn diyawo
Kuro n'bẹ, this kind power na super
Nawọ si nnkan, to ba fẹ gbogbo ẹ la ma ra, wo
This kind na super power
Niṣo ninu yara ka lọ dara
[Verse 4]
Ori owo o dori ọmọ
A ti ri kini ka ṣe dori ọkọ
Orin dowo o, orin dọla
Orin di pound sterling, euro ati dollar
[Chorus]
Wọn a wa, wọn a wa niwa iyawo
Oloṣo ni wọn, wọn fẹ ka sọ wọn diyawo
Wa, wọn a wa, wọn a wa niwa iyawo
Aṣọmu ni wọn, wọn fẹ ka sọ wọn diyawo
[PreChorus]
I get power to do one hour
Your baby mama give you left over
She come my palace, she wan sleepover
This kind power na super power
Na super power
Written by: Abayomi Adetunji, Chisom Ezeh, David Adeleke, Omoniyi Temidayo
instagramSharePathic_arrow_out