Top Songs By Teejay’s WRLD
Credits
AUSFÜHRENDE KÜNSTLER:INNEN
Teejay’s WRLD
Künstler:in
KOMPOSITION UND LIEDTEXT
Teejay’s WRLD
Arrangeur:in
PRODUKTION UND TECHNIK
PM
Produzent:in für Gesangsaufnahmen
Lyrics
[Intro]
IMOLE!!!
Bhad man tinz!
[Verse 1]
Mo silent mood but beast ni mi
Mo le cause violence but still, peace ni mi
You don't have to hurt me, before you win
You don't have to kill somebody before you sin
[Verse 2]
I look up to the sky I only see the birds
I noticed them dancing and nodding their heads
They only give praise to the creator of the earth
Let praise Allah, Allah, Allahu Akbar
[Verse 3]
Yah Robi jọ, ahn, ma wo mi niran
Wa duro ti mi, jọ ma jẹ ki n fi ọjọ ọlọjọ lọ
Tori idunnu mi kọ ni gbogbo eeyan fẹ ri
Ẹ n tan ra yin ni, ẹyin ti ẹ ro boya ẹ le fi mi ṣẹsin
[Verse 4]
Ah, see life, aye ma le oh
Wọn ba a fẹyin titi ti, ẹ wo ibi ti wọn sun Mohbad de
O ṣẹlẹ tan n'sin ko s'ẹni to fẹ dide
A mọ iru yin oju aye, repost nikan naa lẹ n ṣe
[Verse 5]
Ah, I may be moving slow, just believe u can't stop me
Cause this life wey we dey it isn't f***** easy
Only fear God and be afraid of nothing
Kala, sanju, jẹ koju aanu ẹ fọ n'sin
[Verse 6]
Never complain, bruh never explain
I only want you to scream when you feel the pain
Ile-aye yii na everything go end
Ẹyin tẹ n tafa sinu imọlẹ boya kẹ ma ku mọ
[Verse 7]
Ah, ẹpa Odogwu Mara iyẹn lọ bẹẹ
Dabliz nkọ? Ẹ ti mu kuro nilẹ
Mohbad la tun mọ bi ti ẹ ṣe jẹ yii
Alimutu iku, ah iku, o ku iṣẹ
[Outro]
September 20, Nigeria flag turns "Green Red Green"
Bahd man
Rip to the protesters
Written by: Teejay’s WRLD