Similar Songs
Credits
AUSFÜHRENDE KÜNSTLER:INNEN
Niniola
Künstler:in
KOMPOSITION UND LIEDTEXT
Niniola
Songwriter:in
MICHAEL NDIKA
Songwriter:in
Lyrics
[Verse 1]
A ko wọn jọ
You fit take am for holiday, she heavy gan-an
Working every night and day to buy mansion (Mansion)
Ṣẹkẹrẹ de, ṣẹkẹrẹ de
Ṣẹkẹrẹ ma ju
[Chorus]
Ọmọ yẹn dun (O dun, o dun)
Ọmọ yẹn sweet
Ọmọ yẹn l'adun
Ọmọ yẹn nice
Owo lo pa
I know I'm nice
T'ọmọ yẹn lọrun
Give her what she likes
[Verse 2]
Ọmọ laarọ, laarọ kutu Monday morning
Ọmọkọmọ pẹlu OG with the money
Ọmọ laarọ, laarọ kutu Monday morning
Ọmọkọmọ pọju lori, lori agbo
[Bridge]
Kaaarọ o jiire
Ti n ba ti na kini kale (Kale, kale, kale)
[Verse 3]
How long can you tọju me for?
My head touch my toes
Just think about it
Ṣo le tọju mi to?
Now and forever more
[Chorus]
Ọmọ yẹn dun
Ọmọ yẹn sweet
Ọmọ yẹn dun-dun
Ọmọ yẹn nice
Owo lo pa
I know I'm nice
T'ọmọ yẹn lorun
Give her what she likes
[Verse 4]
Ọmọ laarọ, laarọ kutu Monday morning (Monday morning)
Ọmọkọmọ pẹlu OG with the money
Ọmọ laarọ laarọ kutu Monday morning
Ọmọkọmọ pọju lori, lori agbo
[Chorus]
Ọmọ yẹn dun
Ọmọ yẹn sweet
Ọmọ yẹn l'adun
Ọmọ yẹn nice
Owo lo pa (Owo lo pa)
I know I'm nice
Ọmọ yẹn pọ
Written by: MICHAEL NDIKA, Mpho Talana, Niniola Apata